Lúùkù 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì fi agbára Ẹ̀mí padà wá sí Gálílì: òkìkí rẹ̀ sì kàn kálẹ̀ ní gbogbo agbègbè tí ó yí i ká.

Lúùkù 4

Lúùkù 4:7-21