Lúùkù 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nísinsìnyí pẹ̀lú, a fi àáké lé gbòǹgbò igi náà: gbogbo igi tí kò bá so èso rere, a ké e lulẹ̀, a sì wọ́ ọ jù sínú iná.”

Lúùkù 3

Lúùkù 3:3-18