Lúùkù 3:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí í ṣe ọmọ Ámínádábù, tí íṣe ọmọ Rámù,tí í ṣe ọmọ Ésírónì, tí í ṣe ọmọ Fárésì,tí í ṣe ọmọ Júdà.

Lúùkù 3

Lúùkù 3:23-38