Lúùkù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí Ánásì òun Káíáfà ń ṣe olórí àwọn àlùfáà, nígbà náà ni ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tọ Jòhánù ọmọ Sakaráyà wá ní ijù.

Lúùkù 3

Lúùkù 3:1-11