Lúùkù 3:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dáhùn ó sì wí fún wọn pé, “Ẹni tí ó bá ní ẹ̀wù méjì, kí ó fi ọ̀kan fún ẹni tí kò ní; ẹni tí ó bá sì ní oúnjẹ, kí ó ṣe bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú.”

Lúùkù 3

Lúùkù 3:2-12