Lúùkù 24:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì mú wọn jáde lọ títí wọ́n fẹ́rẹ̀ dé Bétanì, nígbà tí ó sì gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè, ó súre fún wọn.

Lúùkù 24

Lúùkù 24:47-53