Lúùkù 24:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ wo ọwọ́ mi àti ẹsẹ̀ mi, pé èmi tìkarami ni! Ẹ dì mí mú kí ẹ wò ó nítorí tí iwin kò ní ẹran àti egungun lára, bí ẹ̀yin ti rí tí èmi ní.”

Lúùkù 24

Lúùkù 24:29-45