Lúùkù 24:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ọjọ́ ọ̀sẹ̀, àwọn obìnrin wá sí ibojì, wọ́n sì mú lọ́fíńdà ti wọ́n tí pèsè sílẹ̀ wá.

2. Òkúta ti yí kúrò ní ẹnu ibojì.

3. Nígbà tí wọ́n sì wọ inú rẹ̀, wọn kò rí òkú Jésù Olúwa.

Lúùkù 24