Lúùkù 23:55 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti àwọn obìnrin, tí wọ́n bá a ti Gálílì wá, tí wọ́n sì tẹ̀lé, wọ́n kíyèsí ibojì náà, àti bí a ti tẹ́ òkú rẹ̀ sílẹ̀.

Lúùkù 23

Lúùkù 23:46-56