Lúùkù 23:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti gbogbo àwọn ojúlùmọ̀ rẹ̀, àti àwọn obìnrin tí ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn láti Gálílì wá, wọ́n dúró lókèrè, wọ́n ń wo nǹkan wọ̀nyí.

Lúùkù 23

Lúùkù 23:39-54