Lúùkù 23:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pílátù sì wí fún àwọn Olórí àlùfáà àti fún ìjọ ènìyàn pé, “Èmi kò rí ẹ̀ṣẹ̀ lọ́wọ́ Ọkùnrin yìí.”

Lúùkù 23

Lúùkù 23:1-13