Lúùkù 22:59 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tó bí i wákàtí kan síbẹ̀ ẹlòmíràn tẹnumọ́ ọn, wí pé, “Nítòótọ́ eléyìí náà wà pẹ̀lú rẹ̀: nítorí ará Gálílì ní í ṣe.”

Lúùkù 22

Lúùkù 22:50-62