Lúùkù 22:56 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọbìnrin kan sì rí i bí ó ti jókòó níbi ìmọ́lẹ̀ iná náà, ó sì tẹjúmọ́ ọn, ó ní, “Eléyìí náà wà pẹ̀lú rẹ̀.”

Lúùkù 22

Lúùkù 22:54-58