Lúùkù 22:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wí pé, “Baba, bí ìwọ bá fẹ́, gba ago yìí lọ́wọ́ mi: ṣùgbọ́n ìfẹ́ ti èmi kọ́, bí kò ṣe tìrẹ ni kí à ṣe.”

Lúùkù 22

Lúùkù 22:32-52