Lúùkù 22:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti àwọn olórí àlùfáà, àti àwọn akọ̀wé ń wá ọ̀nà tí wọn ìbá gbà pa á; nítorí tí wọn ń bẹ̀rù àwọn ènìyàn.

Lúùkù 22

Lúùkù 22:1-4