Lúùkù 22:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì gba aago, nígbà tí ó sì ti dúpẹ́, ó wí pé, “Gba èyí, kí ẹ sì pín in láàrin ara yín.

Lúùkù 22

Lúùkù 22:15-22