Lúùkù 21:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwọn kan sì ti ń sọ̀rọ̀ ti tẹ́ḿpílì, bí a ti fi òkúta dáradára àti ẹ̀bùn ṣe é ní ọ̀ṣọ́, ó ní,

Lúùkù 21

Lúùkù 21:1-7