Lúùkù 21:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ọjọ́ ẹ̀san ni ọjọ́ wọ̀nyí, kì a lè mú ohun gbogbo tí a ti kọ̀wé rẹ̀ ṣẹ.

Lúùkù 21

Lúùkù 21:13-23