Lúùkù 20:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò sì lè gbá ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú níwájú àwọn ènìyàn: ẹnu sì yà wọ́n sí ìdáhùn rẹ̀, wọ́n sì pa ẹnu wọn mọ́.

Lúùkù 20

Lúùkù 20:21-30