Lúùkù 20:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnikẹ́ni tí ó ṣubú lu òkúta náà yóò fọ́; ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí òun bá subú lù, yóò lọ̀ ọ́ lúúlúú.”

Lúùkù 20

Lúùkù 20:17-27