Lúùkù 20:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò wá, yóò sì pa àwọn alágbàtọ́jú náà run, yóò sì fi ọgbà àjàrà náà fún àwọn ẹlòmíràn.” Nígbà tí wọ́n sì gbọ́, wọ́n ní, “Kí a má ri I!”

Lúùkù 20

Lúùkù 20:13-26