Lúùkù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn olùsọ́-àgùntàn ńbẹ tí wọ́n ń gbé ní ìlú náà, wọ́n ń sọ́ agbo àgùntàn wọn ní òru ní pápá tí wọ́n ń gbé.

Lúùkù 2

Lúùkù 2:4-17