Lúùkù 2:52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì ń pọ̀ ní ọgbọ́n, sì ń dàgbà, ó sì wà ní ojúrere ní ọ̀dọ̀ Ọlọ́run àti ènìyàn.

Lúùkù 2

Lúùkù 2:45-52