Lúùkù 2:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ náà sì ń dàgbà, ó sì ń lágbára, ó sì kún fún ọgbọ́n: oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run sì ń bẹ lára rẹ̀.

Lúùkù 2

Lúùkù 2:35-44