Lúùkù 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóṣéfù pẹ̀lú sì gòkè láti Násárẹ́tì ìlú Gálílì, sí ìlú Dáfídì ní Jùdéà, tí à ń pè ní Bétílẹ́hẹ́mù; nítorí ti ìran àti ìdílé Dáfídì ní í ṣe,

Lúùkù 2

Lúùkù 2:1-10