Lúùkù 2:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wólẹ̀ ní àkókò náà, ó sì dúpẹ́ lọ́wọ́ Olúwa pẹ̀lú, ó sì sọ̀rọ̀ rẹ̀ fún gbogbo àwọn tí ó ń retí ìdáǹdè Jerúsálémù.

Lúùkù 2

Lúùkù 2:30-44