Lúùkù 2:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa alágbára, nígbàyí ni o tó jọ̀wọ́ ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ lọ́wọ́ lọ,Ní àlààáfíà, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ rẹ:

Lúùkù 2

Lúùkù 2:20-33