Lúùkù 2:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(Bí a ti kọ ọ́ sínú òfin Olúwa pé, “Gbogbo ọmọ ọkùnrin tí ó ṣe àkọ́bí, òun ni a ó pè ní mímọ́ fún Olúwa”),

Lúùkù 2

Lúùkù 2:20-24