Lúùkù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni yóò sì ṣe àmì fún yín; ẹ̀yin yóò rí ọmọ-ọwọ́ tí a fi ọ̀já wé, ó dùbúlẹ̀ ní ibùjẹ ẹran.

Lúùkù 2

Lúùkù 2:10-17