Lúùkù 19:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ń wí pé, “Ìbáṣepé ìwọ mọ̀, lóní yìí, àní ìwọ, ohun tí í ṣe tí àlààáfíà rẹ! Ṣùgbọ́n nísinsin yìí wọ́n pamọ́ kúrò lójú rẹ.

Lúùkù 19

Lúùkù 19:40-48