Lúùkù 19:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wí pé, “Ẹ lọ sí ìletò tí ó kọjú sí yín; nígbà tí ẹ̀yin bá wọ̀ ọ́ lọ, ẹ̀yin ó rí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kan tí a so, tí ẹnikẹ́ni kò gùn rí: ẹ tú u, kí ẹ sì fà á wá.

Lúùkù 19

Lúùkù 19:26-33