Lúùkù 19:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo wí fún yín pé, ‘Ẹnikẹ́ni tí ó ní, ni a ó fifún, àti lọ́dọ̀ ẹni tí kò ní èyí tí ó ní pàápàá a ó gbà á lọ́wọ́ rẹ̀.

Lúùkù 19

Lúùkù 19:21-27