Lúùkù 19:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ó sì wí fún àwọn tí ó dúró létí ibẹ̀ pé, ‘Ẹ gba owó mínà náà lọ́wọ́ rẹ̀, kí ẹ sì fi í fún ẹni tí ó ní owó mínà mẹ́wàá.’

Lúùkù 19

Lúùkù 19:15-25