Lúùkù 18:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo wí fún yín, yóò gbẹ̀san wọn kánkán! Ṣùgbọ́n nígbà tí Ọmọ Ènìyàn bá dé yóò ha rí ìgbàgbọ́ ní ayé bí?”

Lúùkù 18

Lúùkù 18:1-16