Lúùkù 18:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójúkan náà ó sì ríran, ó sì ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn, ó sì ń yin Ọlọ́run lógo àti gbogbo ènìyàn nígbà tí wọ́n rí i, wọ́n fi ìyìn fún Ọlọ́run.

Lúùkù 18

Lúùkù 18:33-43