Lúùkù 18:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Opó kan sì wà ní ìlú náà, ó sì ń tọ̀ ọ́ wá, wí pé, ‘Gbẹ̀san mi lára ọ̀ta mi!’

Lúùkù 18

Lúùkù 18:1-11