Lúùkù 18:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pé, “Àwọn ọkùnrin méjì gòkè lọ sí tẹ́ḿpílì láti gbàdúrà, ọ̀kan jẹ́ Farisí, èkejì sì jẹ́ agbowó òde.

Lúùkù 18

Lúùkù 18:2-14