Lúùkù 17:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbá sàn fún un kí a so ọlọ mọ́ ọn ní ọrùn, kí a sì gbé e jù sínú òkun, ju kí ó mú ọ̀kan nínú àwọn kékeré wọ̀nyí kọsẹ̀

Lúùkù 17

Lúùkù 17:1-8