Lúùkù 17:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wólẹ̀ lẹ́bàá ẹsẹ̀ rẹ̀, ó ń dúpẹ́ ní ọwọ́ rẹ̀: ará Samáríà ni òun í ṣe.

Lúùkù 17

Lúùkù 17:13-20