Lúùkù 16:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn Farisí, tí wọ́n ní ojúkòkòrò sì gbọ́ gbogbo nǹkan wọ̀nyí, wọ́n sì yọ sùtì sí i.

Lúùkù 16

Lúùkù 16:6-17