Lúùkù 15:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Tàbí obìnrin wo ni ó ní fàdákà mẹ́wàá bí ó bá sọ ọ̀kan nù, tí kì yóò tan fìtílà, kí ó fi gbá ilé, kí ó sì wá a gidigidi títí yóò fi rí i?

Lúùkù 15

Lúùkù 15:1-14