Lúùkù 14:34-35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

34. “Iyọ̀ dára: ṣùgbọ́n bí iyọ̀ bá di òbu, kínni a ó fi mú un dùn?

35. Kò yẹ fún ilẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò yẹ fún ààtàn; bí kò ṣe pé kí a kó o dànù.“Ẹni tí ó bá ní etí láti fi gbọ́ kí ó gbọ́.”

Lúùkù 14