Lúùkù 14:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó má baà jẹ́ pé nígbà tí ó bá fi ìpìlẹ̀ ilé sọlẹ̀ tan, tí kò lè parí rẹ̀ mọ́, gbogbo àwọn tí ó rí i a bẹ̀rẹ̀ sí í fi í ṣe ẹlẹ́yà.

Lúùkù 14

Lúùkù 14:24-30