Lúùkù 14:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa náà sì wí fún ọmọ ọ̀dọ̀ náà pé, ‘Jáde lọ sí òpópó, àti sí ọ̀nà ọgbà, kí o sì rọ̀ wọ́n láti wọlé wá, kí ilé mi lè kún.

Lúùkù 14

Lúùkù 14:21-30