Lúùkù 13:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo wí fún yín, Bẹ́ẹ̀ kọ́: bí kò se pé ẹ̀yin ronúpìwàdà, gbogbo yín ni yóò ṣègbé bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́.

Lúùkù 13

Lúùkù 13:1-5