Lúùkù 13:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dàbí hóró músítádì, tí ọkùnrin kan mú, tí ó sì sọ sínú ọgbà rẹ̀; tí ó sì hù, ó sì di igi ńlá; àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run sì ń gbé orí ẹ̀ka rẹ̀.”

Lúùkù 13

Lúùkù 13:15-23