Lúùkù 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ológoṣẹ́ márùn ún sáà ni a ń tà lówó idẹ wẹ́wẹ́ méjì? A kò sì gbàgbé ọ̀kan nínú wọn níwájú Ọlọ́run?

Lúùkù 12

Lúùkù 12:2-10