Lúùkù 12:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi sì wí fún yín ẹ̀yin ọ̀rẹ́ mi, ẹ má ṣe bẹ̀rù àwọn tí ó ń pa ara ènìyàn kú, lẹ́yìn èyí, wọn kò sì ní èyí tí wọ́n lè ṣe mọ́.

Lúùkù 12

Lúùkù 12:1-8