Lúùkù 12:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ ta ohun tí ẹ̀yin ní, kí ẹ sì tọrẹ àánú kí ẹ sì pèsè àpò fún ara yín, tí kì í gbó, ìṣúra ní ọ̀run tí kì í tán, ní ibi tí olè kò lè súnmọ́, àti ibi tí kòkòrò kì í bà á jẹ́.

Lúùkù 12

Lúùkù 12:23-36