Lúùkù 12:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí gbogbo nǹkan wọ̀nyí ni àwọn orílẹ̀ èdè ayé lé kiri: Baba yín sì mọ̀ pé, ẹ̀yin ń fẹ nǹkan wọ̀nyí.

Lúùkù 12

Lúùkù 12:27-34